ỌLỌRUN ìyanu / GOD of miracles cannot be explained by natural or scientific laws
ỌLỌRUN to ngbọ adura ninu adura / HE hears the voice of our supplication
ỌLỌRUN ngbe aye kanrin keṣe / HE is from everlasting to everlasting
ỌLỌRUN to gbọ ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lati inu awọn oke wa / HE is a GOD who hears the many mysterious voices from the womb of mountains
BABA ìsalẹ̀ fun gbogbo awọn onigbagbọ ìjìnlẹ̀ / HE is the Mentor and the firm foundation for all saved and sanctified believers
ỌLỌRUN ti ko ni adele / HE is GOD and there is no other
ỌLỌRUN ti o ni olubakẹgbẹ / HE is GOD all by HIMSELF and there is no other but HIM
Agbon nsẹ, oyin na nsẹ, bẹẹ sini oju oloko rẹẹ kọ̀ndu-kọ̀ndu / The wasp is denying and the bee is also denying, yet the face of the farmer is swollen all-over. (The evidences are glaring)
ỌLỌRUN ti o nla ni / HE is GOD who makes rich
ỌLỌRUN ajulọ / HE is GOD who is greater than all
Ko si oloọ̀gun ti ngbani lọwọ adanwọ̀ / No spiritualist or herbalist can save or deliver from trouble. HE is the Great Deliverer
ỌLỌRUN ni ìpinlẹ ati ìkẹhìn / GOD is the First and the Last
Eni ti o ni ibẹrẹ koṣa le ni opin / HE has no beginning can never have an end
EMI ni ỌLỌRUN ti nṣe ọyẹ ti si nṣe òóru / I AM GOD who created time and season: Winter time and Summer time
EMI ni ỌLỌRUN adìitu ti o da sanmọ ti o si da ilẹ pẹ̀pẹ̀ / I AM the Unsearchable GOD who created the heavens and the earth
Emi ni gbogbo ìgba; gbogbo agbara / I AM All Time and Season; I AM Omnipotent
Ko si ẹni ti o le gba ỌLỌRUN ni ìmọran / NO one can counsel YOU… GOD
ỌLỌRUN ti o l’agbara pupọ ninu ìṣẹlẹ̀ / HE is the all-powerful GOD who does mighty and glorious things
ỌLỌRUN ti o le gbe eniyan soke laulau ti o si le rẹ onit’ọhùn silẹ / HE is a GOD who can exalt and honor a man unutterably more than he can ever imagined. HE is also able to abase and demote him.
ỌLỌRUN aṣakẹ ti o n k’eyan de gongo de’bi to ni t’ọhùn fẹ lọla de / HE is an affectionate GOD who loves and blesses men until their cups run-over
Oke ja ju oke OBA ju ọba lọ / My GOD is a KING that is greater than all presidents of nations put together
0 Comments